Content pfp
Content
@
0 reply
0 recast
0 reaction

mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵 pfp
mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵
@mubaranky
Orishirishi Ounje Nile Yoruba Ounje Yoruba ma dun gidigan eyi ni awon ounje orisirisi ti o wa ni ile yoruba. LAFUN, IYAN, IKOKORE,EBIRIPO, ASARO ati beebee lo. oasalaye die ninu won IYAN: awon Yoruba a maa so wipe iyan to wewu egusi,to de fila isapa….I-Y-A-N. a baa lowo awon baba nla wa o si je ounje to gbayi julo nile Yoruba.isu lama gun felefele ninu odo titi yo fi di iyan a le fi isapa je tabi obe egusi sugbon obe to tayo julo ni obe efo elegusi tabi riro ki a wa fi eran igbe de lade. a le fi emu ogidi sin losale. Sokoyokoto olobe loloko
10 replies
4 recasts
11 reactions

Kelvin pfp
Kelvin
@kel66
Òúnjé bétá léléyí óó
1 reply
0 recast
1 reaction

rstlxstudio 🍖🎩 pfp
rstlxstudio 🍖🎩
@rest
Iyannnnn 🥹😭😭 Mo dé fe sunkun shaaa 😭 Odun gaan
1 reply
0 recast
0 reaction

Kamal🍀🍄🎩🔵🥭🎭 pfp
Kamal🍀🍄🎩🔵🥭🎭
@kamadin.eth
Mo feran iyan gan
1 reply
0 recast
0 reaction

Mohammed 🍖🔵 🎩🥭 pfp
Mohammed 🍖🔵 🎩🥭
@bigmoh
Mo ni fe iyan gidigan
1 reply
0 recast
0 reaction

Msh🥭🎩🎭🔊🔫 pfp
Msh🥭🎩🎭🔊🔫
@muhsee
Ounje gidi
1 reply
0 recast
0 reaction

The Real Ghost 👻🎩🍖📖 pfp
The Real Ghost 👻🎩🍖📖
@ghost58
Iyan ni seh!!! Kosi ounje Miran to dun to iyan😋😋
1 reply
0 recast
0 reaction

sierrarenee ayomikun folashade pfp
sierrarenee ayomikun folashade
@juujuumama
100 $DEGEN 🤤
1 reply
0 recast
0 reaction

rstlxstudio 🍖🎩 pfp
rstlxstudio 🍖🎩
@rest
Iyan je okan ninu ounje timo feran gaaan 🎭
0 reply
0 recast
0 reaction

sailor pfp
sailor
@sailo
mo fe ran iyan pupo
0 reply
0 recast
0 reaction

goodness 🎭 pfp
goodness 🎭
@goodex
Hmm Òúnjé bétá léléyí óó
0 reply
0 recast
0 reaction