Content pfp
Content
@
0 reply
0 recast
0 reaction

mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵 pfp
mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵
@mubaranky
Orishirishi Ounje Nile Yoruba Ounje Yoruba ma dun gidigan eyi ni awon ounje orisirisi ti o wa ni ile yoruba. LAFUN, IYAN, IKOKORE,EBIRIPO, ASARO ati beebee lo. oasalaye die ninu won IYAN: awon Yoruba a maa so wipe iyan to wewu egusi,to de fila isapa….I-Y-A-N. a baa lowo awon baba nla wa o si je ounje to gbayi julo nile Yoruba.isu lama gun felefele ninu odo titi yo fi di iyan a le fi isapa je tabi obe egusi sugbon obe to tayo julo ni obe efo elegusi tabi riro ki a wa fi eran igbe de lade. a le fi emu ogidi sin losale. Sokoyokoto olobe loloko
10 replies
4 recasts
11 reactions

Kelvin pfp
Kelvin
@kel66
Òúnjé bétá léléyí óó
1 reply
0 recast
1 reaction

mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵 pfp
mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵
@mubaranky
beeni oremi ounje gidi ni
0 reply
1 recast
1 reaction