Content pfp
Content
@
0 reply
0 recast
0 reaction

mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵 pfp
mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵
@mubaranky
Àṣà ìsọmọlórúkọ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn àṣà ilẹ̀ Yorùbá. Orúkọ ṣe pàtàkì gan-an, ó sì ṣe kókó. Gbogbo ohun tí Ọlọ́run dá pátá ló ní orúkọ tí wọ́n ń jẹ́. Kí a ba lè dá ẹnikọ̀ọ̀kan mọ̀ ni a ṣe máa ń fún wọn lórúkọ. Yorùbá gbàgbọ́ pé orúkọ á máa fi bí ọmọ ṣe jẹ́ hàn, orúkọ á sì máa ro ọmọ, àti pé orúkọ ọmọ ni ìjánu ọmọ. Oríṣịríṣị àkíyèsi ni àwọn òbí máa ń ṣe kí wọ́n tó lè pinnu orúkọ tí wọ́n máa fún ọmọ. Wọ́n máa ń ṣe àkíyèsi ipò tí ọmọ wà nígbà tí a bí i, wọ́n tún máa ń ṣe àkíyèsi ipò tí ẹbí wà lásìkò tí wọ́n bí ọmọ náà, ìṣẹ̀lẹ̀ tó ṣẹ̀ ní kété tí wọ́n bí ọmọ náà, tàbí ìṣẹ̀lẹ̀ tó ṣẹ̀ nígbà tí ìyá rẹ̀ wà nínú oyún ọmọ náà.
1 reply
1 recast
4 reactions

OLOFIN 🎩🎭🍖🐹⛓️ pfp
OLOFIN 🎩🎭🍖🐹⛓️
@sunkanmi
O seun ọmọ ìyá mofun alaye yii 5 $DEGEN
3 replies
0 recast
0 reaction

$DEGEN Tip Bot pfp
$DEGEN Tip Bot
@degentipbot.eth
✅ 5 tipped ∙ 0 remaining 5 / 5 (100%) ✅✅✅✅✅✅✅✅✅✅ Dune snapshot: 06-30 ✅
0 reply
0 recast
0 reaction

$DEGEN Tip Bot pfp
$DEGEN Tip Bot
@degentipbot.eth
@sunkanmi, LAST CHANCE: there is 00h 14m until reset and you still have 5 DEGEN left to tip. Happy tipping!
0 reply
0 recast
0 reaction

$DEGEN Tip Bot pfp
$DEGEN Tip Bot
@degentipbot.eth
@sunkanmi, there is 00h 53m until reset and you still have 5 DEGEN left to tip. Happy tipping!
0 reply
0 recast
0 reaction