horla.base.eth pfp
horla.base.eth
@horlami
ÒRÒMỌDÌRẸ TÓ Ń BÁ ÀṢÁ ṢERÉ, Ó KÚKÚ ṢE BÍ ẸYẸ OKO TÍ Ó Ń BÁ ẸYẸ MÌÍRÀN WO ỌMỌ NI. TRANSLATION Due to a mistaken assumption, a chick engages in play with a hawk, incorrectly perceiving it as a caring bird from the jungle. MORAL Poor and uninformed assumptions and misconceptions can lead to unexpected consequences. Nínú ọdún yìí Ọlọrun Yóò nu omijé ojú wa nù kúrò, Yóò sì sọ ẹkún wa di ẹ̀rín l'áṣẹ Èdùmàrè. ÀMÍN
0 reply
0 recast
0 reaction

Shefman24🎩🎩 🎭⚡🥜 pfp
Shefman24🎩🎩 🎭⚡🥜
@shefman24
Amin, Òro Àgbà.
0 reply
0 recast
0 reaction