0 reply
0 recast
0 reaction
ADURA OWURO,
"E jo wo ooo,
E je ka jo jo gba Imisi Adura yi o"
"Adeda wa ooo!!!
A wa hun du pe ni owo yin,
Fun ki ka wa ye ge ge bi,
Iseda ti o ni eje ni Orun,
Ti a si tun ni ahunfani a ti mo min si oke si odo,
A wa ko si ni ipo oku,
Ipo Alaaye okan ni e pin wa si lo ni,
Opolopo Ope ni o ye fun yin ni igba gbogbo,
E wa ba wa gba Ope ti a wa hun fi igba gbogbo hun du si yin,
E wa so oke ti ota wa ko si wa ni igbaya wa di petele,
Ki e si ba wa so gbogbo agbara ibi won di Ofo, 3 replies
0 recast
6 reactions
0 reply
0 recast
0 reaction