Content pfp
Content
@
0 reply
0 recast
0 reaction

mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵 pfp
mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵
@mubaranky
ASA IGBEYAWO NI ILE YORUBA orisi igbeyawo meji ni owa akoko igbeyawo abinibi ekeji igbeyawo aye ode oni Eyi ti a fe soro lori re bayi ni: IGBEYAWO ABINIBI O je Igbeyawo aye atijo ti awon baba nla awon Yoruba fi eto re lele, ni ile Yoruba ni aye atijo, ti omokunrin ba ti ba laga, awon obi i re koni je ki o sunmi, o di dandan ki o fe aya. Sugbon ki o to le fe aya o ni awon ohun ti o pon dandan fun un lati se ki o ba le ni ayorisi ti o dara. Awon wonyin ni a n pe ni igbese Igbeyawo Abinibi.
7 replies
0 recast
2 reactions

sailor pfp
sailor
@sailo
olohun 🎭
0 reply
0 recast
0 reaction