Content pfp
Content
@
0 reply
0 recast
0 reaction

SegNik🎩🎭✨️🍖 pfp
SegNik🎩🎭✨️🍖
@segnik
ÀSÌKÒ MẸ́FÀ TÍ Ó YÉ LÁTI MÁA MÚ OMI TÓLỌ́WỌ́Ọ́RỌ́: 1. Bí a bá jí gbàrà. 2. Ọgbọ́n ìṣẹ́jú ṣáájú oúnjẹ. 3. Bí ó bá ń rẹni. 4. Ṣáájú kí a tó fégbẹ́lélẹ̀. 5. Lẹ́yìn iṣẹ́. 6. Nígbà tí ara bá gbẹ́. ÀǸFÀÀNÍ: * Yíyàgbẹ́ wọ́rọ́wọ́ * Yóò dẹkùn dídì ọ̀rá inú ẹ̀jẹ̀ * kìí jẹ́ kí ó rẹni. * Lé ẹ̀jẹ̀ ríru lọ * Jíjá sísanra kù. * Lílọ oúnjẹ kúnná ní kíá. * Àìsàn yóò sá lọ pátápátá. * Ara yóò máa jọ̀lọ̀ * Apa kòkòrò búburú ní àgọ̀ ara * Ìdènà arunmọléegun Oro ilera wa se koko.
2 replies
0 recast
3 reactions

Cryptobetty pfp
Cryptobetty
@prettybetty
Eseun fun awon alaye yii 250 $wild
0 reply
0 recast
1 reaction