Content pfp
Content
@
0 reply
0 recast
0 reaction

Madam Suzie💎🌴 pfp
Madam Suzie💎🌴
@madam-suzie
The Yoruba civilization has always revered twins so much that we have an Orisa called Orisa Ibeji 🤍 Oriki Ibeji Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún. Ẹdúnjobí Ọmọ ẹdun tíí ṣeré orí igi Ọ́-bẹ́-kẹ́ṣé-bẹ́-kàṣà, Ó fẹsẹ̀ méjèèjì bẹ sílé alákìísa; Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, Tíí gbàdọ̀bálẹ̀ lọ́wọ́ baba tó bí í lọ́mọ Wínrinwínrin lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀. Tani o bi ibeji ko n'owo?
2 replies
0 recast
2 reactions

SierraRenee Ayọ Ṣádé pfp
SierraRenee Ayọ Ṣádé
@juujuumama
E seun! Eleyi wuni gaan, Oriki Ibeji yi dara pupo. 100 $DEGEN
0 reply
0 recast
0 reaction

Madam Suzie💎🌴 pfp
Madam Suzie💎🌴
@madam-suzie
Olodumare a se fun yin💜💜💜
0 reply
0 recast
1 reaction