Content
@
https://warpcast.com/~/channel/base-yoruba
0 reply
0 recast
0 reaction
CRYPTLAOAT🎩Ⓜ️🍓🌲🎭
@laoat
Àgbà tí kò bínú lọmọ rẹ̀ ń pọ̀ jọjọ. Translation A serene and even-tempered elderly person is best equipped to navigate the demands of raising a large family. Moral Enduring love and patience are the anchors of a successful family life. Bi ọdun yi ṣe npari lọ, a kòní da aṣọ ọfọ bora. Ogún rọju jẹ, rọju mu; kòní jẹ tìwa laṣẹ Èdumare. A ku Ojúmọ́
4 replies
0 recast
3 reactions
SegNik🎩🎭✨️🍖
@segnik
Ọmọ rẹ̀ á pọ̀
0 reply
0 recast
0 reaction
OLOFIN 🎩 🎭🌲🍓
@sunkanmi
16 👏
0 reply
0 recast
0 reaction
Ayushadex Ⓜ️🎩🐹🍖🎭
@ayushadex
Beeeni oo baaami 😂, mo gbàgbó
0 reply
0 recast
0 reaction
Johnson
@olakayodej
Agba 🎭
1 reply
0 recast
0 reaction