Content
@
0 reply
0 recast
0 reaction
CRYPTLAOAT🎩Ⓜ️🍓🌲🎭
@laoat
IṢẸ́ NI ÒGÚN IṢÉ Múra sí iṣẹ́ Ọ̀rẹ́ mi Isẹ́ ni afí ń d'ẹni gíga Bí akò bá r'ẹ́ni f'ẹ̀yìn'tì Bí ọ̀lẹ là á rí Bí a kò bá r'ẹ́ni gbẹ́kẹ̀lé Á tẹra mọ́ isẹ́ ẹni Ìyá rẹ lè l'ówó l'ọ́wọ́ Bàbá rẹ́ sì lè l'ẹ́shin lé kan Bí o bá gb'ójú lé wọn O tẹ́ tán ni mo sọ fún ọ Ohun tí a kò bá j'ìyà fún Ṣé kìí lè t'ọ́jọ́ rárá Ohun tí a bá f'ara ṣiṣẹ́ fún Ní npẹ́ l'ọ́wọ́ ẹni Apá l'ará Ìgúpá nì ìyè kàn Bí aiyé bá ńfẹ ọ lónìí Tí o bá l'ówó l'ọ́wọ́ Ayé á máa fẹ́ ọ lọ́lá Jẹ́kí o wà ní ipò àtàtà Aiyé á ma yẹ́ ọ sí t'ẹ̀rín-t'ẹ̀rín Jẹ́kí ó d'ẹni tí ń ràgò Kó o rí bí aiyé tí n yín'mú sí ọ Ẹ̀kọ́ sì lè ṣ'ẹni d' ọ̀gá Múra kí o kọ dáradára Bí o rí ọ̀pọ́ ènìyàn Tí ń fi ẹ̀kọ́ ṣẹ̀ rín rín A'ku osu tuntun
0 reply
0 recast
0 reaction