Content pfp
Content
@
0 reply
0 recast
0 reaction

SierraRenee Ayọ Ṣádé pfp
SierraRenee Ayọ Ṣádé
@juujuumama
Mo ti pari iwure ati ibori mi, mo setan lati bere ojo mi pelu aduroti awon baba nla mi ati Olodumare 🙏
7 replies
2 recasts
9 reactions

mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵 pfp
mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵
@mubaranky.eth
ki ibi gbogbo ki re kuro ni ore re pelu ase eledumare 💜
0 reply
0 recast
2 reactions

OLOFIN 🎩 🎭🌲🍓 pfp
OLOFIN 🎩 🎭🌲🍓
@sunkanmi
Iwure yin koni sai gba lase awon igba irun monle
0 reply
0 recast
1 reaction

Dvyne pfp
Dvyne
@dummie.eth
Amin
0 reply
0 recast
1 reaction

FBI Ⓜ️🍄💼🎩🍖 pfp
FBI Ⓜ️🍄💼🎩🍖
@bolakakefuad
Olodumare a jeko ronrun fun yin sister mi @juujuumama
0 reply
0 recast
1 reaction

Senior.base.eth🎩🔵 pfp
Senior.base.eth🎩🔵
@senior01.eth
Ki olohun fi alubarika si ojo eni fun gbogbo wa
0 reply
0 recast
0 reaction

D-wayne 🎩⚡🎭 pfp
D-wayne 🎩⚡🎭
@drrrner
Amin. Oluwa a fun e l'adura ati idunnu ninu gbogbo awọn ibi ti o wọ ninu ayeye rẹ. Olorun yoo je ki awọn baba nla rẹ ati Olodumare jeki o ni idunnu l'ọjọ ti o wọ. Ase. 🙏
0 reply
0 recast
0 reaction