Content pfp
Content
@
0 reply
0 recast
0 reaction

mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵 pfp
mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵
@mubaranky
ni aye ati jo ki awon elesin musulumi ati awon elesin crisiteni to de. nkan ti an pe ni adura ni ode oni, iwure ni onje ni ile yoruba. itumo iwure je iwu- to uproot ire - good fortune ako jo po majeji wa bi itumo rere
18 replies
8 recasts
14 reactions

sierrarenee ayomikun folashade pfp
sierrarenee ayomikun folashade
@juujuumama
O dara pupo O daju pe iwure ni ohun pataki ninu asa ati isese Yoruba, ti o tumo si ifisun rere ati ise aladuro fun ire ati ayo ninu aye
1 reply
0 recast
0 reaction

mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵 pfp
mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵
@mubaranky
beeni oremi, aori ire ati ayo ninu aye wa ooo
0 reply
0 recast
0 reaction