Content pfp
Content
@
0 reply
0 recast
0 reaction

SierraRenee Ayọ Ṣádé pfp
SierraRenee Ayọ Ṣádé
@juujuumama
E kaaro 🌞 Loni, mo maa lo si MOMA ni New York City, mo maa ri awon irinse iran Yoruba atijo ♥️
0 reply
0 recast
0 reaction

KaⓂ️al🔵🎩 pfp
KaⓂ️al🔵🎩
@kamadin.eth
E kaaro Oda oo Odabo E so layo
0 reply
0 recast
1 reaction

Lolamewu  pfp
Lolamewu
@lolamewu
Yoruba yin ma ti da gan o, e ku ise 👏
0 reply
0 recast
1 reaction

Ⓜ️sh🥭🎩🎭🔊🔫 pfp
Ⓜ️sh🥭🎩🎭🔊🔫
@muhsee
Ekaaro o iPade yin ayori si rere o
0 reply
0 recast
1 reaction

Farouk7️⃣ pfp
Farouk7️⃣
@farouk
E kaaro E yen na da pupo @juujuumama
0 reply
0 recast
1 reaction

mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵 pfp
mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵
@mubaranky.eth
ounti o ba fi oju ba nibe gbiyanju lati fi ran awa olulufe re 5 $degen
0 reply
0 recast
0 reaction

Okiki Olatunde🧉⚽️ pfp
Okiki Olatunde🧉⚽️
@defilord
Yoruba e ti dan pupo Ku ishe takun takun
0 reply
0 recast
0 reaction