Content pfp
Content
@
0 reply
0 recast
0 reaction

SegNik🎩🎭✨️🍖 pfp
SegNik🎩🎭✨️🍖
@segnik
Bí ọdún tí n parí lọ diẹdiẹ, Eléduǹmarè yóò fi ara tú wa ní ìhà gbogbo, Yóò dìde ìrànlọwọ aìnírètí fún ayé wa, Yóò gbé onigbọ̀wọ ti àárẹ kìí mú dide fún wa, Yóò fi ojúrere rogba yìí ayé wa ká, Ọlọ́run kì yóò gba k'ọwọ ota ya lori wa, Yóò gbé wa kọjá ipele Ìjákulẹ, olùrànlọwọ àyànmọ yin yóò wá wa kàn kí ọdún yìí tó parí. Happy Sunday.
1 reply
0 recast
2 reactions

Grace Ville 🎩Ⓜ️🍖 pfp
Grace Ville 🎩Ⓜ️🍖
@graceville
Àmí àṣẹ 🙏 Àṣẹ n tÈdùmàrè 🙏
0 reply
0 recast
1 reaction