Content pfp
Content
@
0 reply
0 recast
0 reaction

mubaranky馃帺,馃幁,馃崉,馃數 pfp
mubaranky馃帺,馃幁,馃崉,馃數
@mubaranky
ADURA OWURO, "E jo wo ooo, E je ka jo jo gba Imisi Adura yi o" "Adeda wa ooo!!! A wa hun du pe ni owo yin, Fun ki ka wa ye ge ge bi, Iseda ti o ni eje ni Orun, Ti a si tun ni ahunfani a ti mo min si oke si odo, A wa ko si ni ipo oku, Ipo Alaaye okan ni e pin wa si lo ni, Opolopo Ope ni o ye fun yin ni igba gbogbo, E wa ba wa gba Ope ti a wa hun fi igba gbogbo hun du si yin, E wa so oke ti ota wa ko si wa ni igbaya wa di petele, Ki e si ba wa so gbogbo agbara ibi won di Ofo,
4 replies
0 recast
4 reactions

goodness 馃幁 pfp
goodness 馃幁
@goodex
脕m铆n 贸贸
0 reply
0 recast
0 reaction