Content pfp
Content
@
0 reply
0 recast
0 reaction

mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵 pfp
mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵
@mubaranky
ODUN EGUNGUN NI ILE YORUBA Ise se je awon asa ati igbagbo awon Yoruba odun eegun si je okan Lara won. Egungun je orisa won a maa pe won ni ara orun Tori igbagbo won ni wipe awon baba won ni won pada lati wa bewon wo lehinti won ti ku. Awon egungun pin si orisirisi. Awon Kan wa eegun alare ni won. Awon Kan wa won a ma se janduku, beeni awon Kan jgunjagun.. Egungun TI a soro le Lori leni no ma pe ni Jemje. Egungun alare ni odiun pupo lati wo botile je wipe omo eegun ni, nitori agba egungun wa. Pattaki juio o je egungun to rewa pupo osi je on I faaji .a maa fa siga a maa muti. A maa ba obinrin soro Ife . O ko yeti seti ati bata eledan ,a maa di tai sorun a maa get fila sori ati we gele . O pidan alawada ati adanilaraya eegun ni a ma Jo Lori orule still ori igi. A maa fo be sile ni ibi to ga , a maa woko ta bi ko wa oko, alupupu tabi Keke. Sugbon ninu Iwa re eleyi ti awon ololufe re ko dun mo ninu ni pe a maa binu. Ko si seni to nfe ibinu re .
3 replies
1 recast
2 reactions

Fashanu 🎭🎩 🍖⚡️👾 pfp
Fashanu 🎭🎩 🍖⚡️👾
@fashtioluwa
Yoruba je ede ijinle wa, proud to be a Yoruba man 🎭
0 reply
0 recast
0 reaction

mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵 pfp
mubaranky🎩,🎭,🍄,🔵
@mubaranky
yoruba sun lede yoruba sun lasa 200 $fomo 20 $wild 5 $degen
1 reply
0 recast
0 reaction