Content
@
0 reply
0 recast
0 reaction
SierraRenee Ayọ Ṣádé
@juujuumama
Orunmila, fi ire gbogbo fun mi Fun ebi mi Fun gbogbo omo Yoruba Ki ire ojo oni wa pelu mi Ki ire ojo ola wa pelu mi Orunmila, jowo, ma je ki n se aseyori Ma je ki n se alaanu Ma je ki n se alagbara Ase
2 replies
0 recast
3 reactions
Bay0
@bay0
Ase
0 reply
0 recast
0 reaction