horla.base.eth
@horlami
A-GBỌ́-ẸJỌ́-ẸNÌKAN DÁ, ÀGBÀ ÒṢÌKÀ NI. TRANSLATION An elder who renders judgment in a dispute after hearing only one party's submission is unjust, wicked, and reprehensible. MORAL A wise mediator seeks balance, fairness, and equity in resolving disputes. Nínú ìjáde lọ àti ìpadà sílé wa lónìí, Ọlọrun alágbára yóò ṣe ọ̀rọ̀ wa ní àṣepé, àṣeyè àti àṣeyege l'áṣẹ Èdùmàrè. AMIN
2 replies
0 recast
25 reactions
Azippy.base.eth 🎩 🎭
@azippy
If there is no fairness, war is about to breakout
0 reply
0 recast
0 reaction