Content pfp
Content
@
0 reply
0 recast
0 reaction

Adeyinka 😍🐹 pfp
Adeyinka 😍🐹
@mercy88
Inú mi á sí máa dùn pé mo jẹ ọmọ Yorùba, Yorùbá bò wọn ní bí afínjú bá woja, a rìn gbendéke, òbún wọjà pa siosio ... Yorùbá ló ni ká rìn ká yan fanda pèlú aşo alárańbarà, gèlè àti filà a se régi lórí àti àwọn ohun òsó tó yáyì. Bí a bá ń sòrò nípa oge Yorùbá ló loge kò sí iyàn lórí rè, àșà Yorùbá kò ní parun,.. Amin oooo
1 reply
0 recast
0 reaction

ayomayowa 🎩🍖🐹⛓️ pfp
ayomayowa 🎩🍖🐹⛓️
@ayomayowa
O Dara pupo 10 $degen
2 replies
0 recast
1 reaction

Adeyinka 😍🐹 pfp
Adeyinka 😍🐹
@mercy88
Ese pupo
0 reply
0 recast
0 reaction

$DEGEN Tip Bot pfp
$DEGEN Tip Bot
@degentipbot.eth
✅ 10 tipped ∙ 94 remaining 1 000 / 1 094 (91%) 🟧🟧🟧🟧🟧🟧🟧🟧🟧⬜ Dune snapshot: 06-22 ✅
0 reply
0 recast
0 reaction