Content
@
https://warpcast.com/~/channel/base-pidgin
0 reply
0 recast
0 reaction
Azippy.base.eth 🎩 🎭
@azippy
ÀJÙMỌ̀BÍ KÒ KAN TÀÁNÚ, ẸNI ORÍ BÁ RÁN SÍNI NÍ Í SENI LÓORE. TRANSLATION Being siblings does not inherently ensure mercy or compassion; rather, it is those whom fate has destined for kindness who will extend goodwill to others. MORAL: In all that we do, may we be agents of mercy and goodness. Ohun tí yóò pa wá l'ẹ́kún nínú ọdún 2025 yìí kò ní ṣẹlẹ̀ síwa l'áṣẹ Èdùmàrè. ÀMÍN Happy new week
31 replies
0 recast
48 reactions
Aduky.base.eth
@aduky
Fact, who go help you no go stress yoi
0 reply
0 recast
1 reaction