Content
@
0 reply
0 recast
0 reaction
gasali🍖🎩🥜
@mutified1
ASA YORÙBÁ. Awọn Yorùbá ni aṣọ orisirisi ti wọn maa n wọ lọ si ayeye ọtọọtọ. Fun apẹẹrẹ ti won baa n se ifọbaje tabi ifinijoye, A o maa da ọba tabi awọn ti wọn fe je oye mọ pelu aṣọ ti o gbayi, ileke ati bata pelu irukere funfun lọwọ wọn.
11 replies
2 recasts
7 reactions
adexmakai.degen.eth
@adexmakai.eth
Hmmm .... okan lara awon asa ati ise ti o gbayi lagbaye. Sugbon o se mi laanu pe a ti un so nu die die.
1 reply
0 recast
1 reaction
gasali🍖🎩🥜
@mutified1
Beni, eni to ba mura bayi lasiko yi, won yio ma fi oju ara oko wo ni, sugbon ti oyinbo bawo ni se ni ao ma kan sara si oyinbo na
1 reply
0 recast
0 reaction