Content
@
https://opensea.io/collection/parentcaster-1
0 reply
0 recast
0 reaction
Nammm
@nihinlolawa
Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún. Ẹdúnjobí Ọmọ ẹdun tíí ṣeré orí igi Ọ́-bẹ́-kẹ́ṣé-bẹ́-kàṣà, Ó fẹsẹ̀ méjèèjì bẹ sílé alákìísa; Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, Tíí gbàdọ̀bálẹ̀ lọ́wọ́ baba tó bí í lọ́mọ. Wínrinwínrin lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀. Tani o bi ibeji ko n'owo? All twins hail from Isokun. A relative of monkeys you are Hoping and jumping from a tree branch to the other Jumping helter-skelter,you landed in a wretched man’s place Turning around his misfortunes A rare set of children that commands undue honour and respect from their parents To your stepmother, you are an unwelcome sight But to your mother, you are both emperors of two empires! Wouldn’t you love to be parents to twins?
29 replies
2 recasts
24 reactions
Obani 🎭
@obani
Yes, i want to have twins 🥜
0 reply
0 recast
0 reaction